Shishe yefun ogede

Ni jakejado agbaye ni won n’je ogede ati agbagba. Nibiti awon kan n’fi ogede she oun’je won ibile, awon kan wa tan to je nikpe eso ni won n’fi she. Kete ti won ba ti she ikore tan, awon ogede nan kii tun kpe nile man, won ma tete baje lati asiko ti won ba n’ko won jo. Shugbon o si shee she ki e yin ogede abi agbagba yin kpada si oun’je mirin bii yefun.

Current language
Yoruba
Need a language?
If you would like this video translated into other languages, please contact kevin@accessagriculture.org
Translated in
Nigeria
Uploaded
3 years ago
Duration
11:45
Produced by
KENAFF, Farm Radio Trust Malawi, UNIDO Egypt, Farmers Media Uganda