Bibojuto oro to wa ninu agbado shi waju ati ni akoko ikore

Iru awon ibadje kan wa ti oni oro ninu, to si je majele eyiti okpolokpo agbe ati onibara ko mo. Awon oro si n’wo inu awon on’je wa. Majele to lagbara le ba ilera yin je lesekese. Ti e ba je awon ounje ti oro o kpo ninu re, yio kpe ki e to shaisan. Oro n’ba edo ati awon kidinrin je.
Current language
Yoruba
Need a language?
If you would like this video translated into other languages, please contact kevin@accessagriculture.org
Translated in
Negeria
Uploaded
3 years ago
Duration
14:00
Produced by
Agro-Insight