Ata sisa ń òrùn

Ti ata ba wa ní tutu, nshe ni o n fura tí o si n bajɛ. Ara awɔn idɔti oloro ti hu jade yi ti o jɛ iwɔ fun eniyan ni a n kpe ni aflatoxine. Lati mu nkan sisa ya laisi idɔti, a le lo awɔn ohun eelo ti fi agbara orun gbɛ awɔn eso ati ɛfɔ. Orishirishi ɛya ati irisi ni awɔn ohun isa ata si orun wɔnyi, shugbɔn ilosi kanna ni wɔn ní.

Current language
Yoruba
Need a language?
If you would like this video translated into other languages, please contact kevin@accessagriculture.org
Uploaded
7 years ago
Duration
11:35
Produced by
Agro-Insight