<<90000000>> viewers
<<240>> entrepreneurs in 17 countries
<<4135>> agroecology videos
<<105>> languages available

Akpakpo Egbe ifowopamo ati owo yiya ni abule

Uploaded 4 years ago | Loading

Nigbati a ba n’fi owo kpamo, ni akpakpo gegebi egbe, a le ran awon ile ishe oloko owo keekeke lowo ki won le dagba ati ki won le ran ara won lowo ni abule. Ninu aworan yii, a o ko bi awon agbe ti Malawi n’shakoso egbe idapo ifowopamosi ati owo yiya ti abule won.

Current language
Yoruba
Produced by
Ronald Udedi
Share this video:

Related Videos

With thanks to our sponsors