Gbigbin gbaguda si ori ile ti o da’gun
Uploaded 5 years ago | Loading
11:49
Ki ile o le maa be ni alaafia a gbodo rii daju pe agbara ojo nla ko woo lo. NInun aworan yi ni ao ti ko eko bi a she le din agbara ku ni oko wa ti ile wa o si maa wa ni alaafia.
Current language
Yoruba
Produced by
Agro-Insight