Igi gbaguda igbalode
Uploaded 5 years ago | Loading
15:40
B'arun ba n ba gbaguda ja, kii ba dara ki agbe o ra igi gbaguda toopoju owo lodo awon ti npese re lagbegbe won. E sora fun lilo igi gbaguda to tii pe lori oko. Ni kete ta ba ge igi gbaguda tan, lo ye ka gbin-in nigba ti awo re tutu minimini. Agbe le se igi gbaguda re lojo fun ojoo mewa, sugbon, eyi ta ge gbodo wole laarin ojoo meji.
Current language
Yoruba
Produced by
Agro-Insight