<<90000000>> viewers
<<240>> entrepreneurs in 17 countries
<<4135>> agroecology videos
<<105>> languages available

Arun mozaique ti gbaguda

Uploaded 5 years ago | Loading

Arun pataki ni arun mozaique je fun gbaguda ti kii je ki o ta daada. Ami ewe ti o pupa resuresu ni a fi maa n damon ni ara ogbin wa. Eshinshin funfun kan ni o maa n ko arun yi ba gbaguda. Arun yi ko gboogun shugbon a lee jinan sii. Lati jinan si arun gbaguda mozaique yi,aribole ti o ni alaafia ni a ni lati gbin. Bee eya gbaguda ti kii gba arun laaye ni ki a gbin. Ti a ba tele awon ilanan yi,arun gbaguda mozaique ko ni ya oko wa,gbaguda wa yoo si ta daada,ere repete ni a o si ri nibe.

Current language
Yoruba
Produced by
Songhaï Centre
Share this video:

With thanks to our sponsors