Pipese wara l'ailo oogun apa Kokoro inun eje
Uploaded 8 years ago | Loading

8:30
Antibiotics je oogun kan ti a n lo lati pa Kokoro aifojuri inun eje ti o maa n fa orishi rishi arun,a le loo lati enun abi ki a gun un ni abere si inun ishan abi s'inun eje,eje yoo gbe oogun yi kiri ara lati pa arun naa ni aaye k'aaye ti o le wa ni ara maalu koda titi de inun wara re.
Current language
Yoruba
Produced by
Agro-Insight