Shishe amojuto eegban ara maalu
Uploaded 8 years ago | Loading

12:40
Kokoro Kekere kan bi awon Kokoro t'oku ni eegban ti o maa n so man ara awon eranko ti yoo si maa mun eje won.Ninun aworan yi awon fulani ni ipinle oyo ni Nigeria yoo she alaye ipalara nla ti eegban n ko ba maalu,bawo ni eegban ti n semi gba ati onan ati k'apa won.
Current language
Yoruba
Produced by
Agro-Insight