<<90000000>> viewers
<<240>> entrepreneurs in 17 countries
<<4135>> agroecology videos
<<105>> languages available

Sise ounje kiki ni owo binti

Uploaded 4 years ago | Loading

E le ra awon ounje ti o ki, to ni eroja kpukpo eyi yoo she iranlowo fun awon eranko yin ki won tete dagba, ki won she wara kpukpo ati eyin. sugbon owo awon ounje wonyi kpo. Bawo ni a she le see awon ounje  gidi to ki fun arawa ni kpoku lowo e?

Current language
Yoruba
Produced by
AIS, MSSRF, WOTR
Share this video:

With thanks to our sponsors