Shishe wara soja
Uploaded 4 years ago | Loading
8:54
Ninu aworan yi, a o wo afihan bi won she n’she wara soja to dara. Te ba fe she wara soja to dara julo, igbese mefa ni a o tele : E yan ke si sha irugbin soja to dara. E re awon irugbin soja nan sinu omi to man ni igba kpuko. E lo awan irugbin nan ninu ero. E yo omi soja nan jade. E se omi soja nan. Ke si yo wara nan kuro ninu re.
Current language
Yoruba
Produced by
DEDRAS