Sisa okpe oyinbo si orun
Uploaded 4 years ago | Loading
7:59
Pupo ope oyinbo lo si n’ baje nitori kpe e o le toju re ju ose kan lo. Nigbati a ba sa ope oyinbo, a le din adanu ku, ki a si jere owo kpukpo titi ikpari odun. Ninu aworan yii, a o she afihan bi e le sa ope oyinbo gbe kpelu ero gbigbe t’oorun, nitori kpe ona yii ni imototo ati pe owo re ko tun kpo.
Current language
Yoruba
Produced by
NOGAMU