E je ki wara o man ki o si tutu
Uploaded 8 years ago | Loading
12:00
Awon ile ishe wara n ba awon asin maalu ati awon a da maalu ra wara ti o je ogidi,won si n soo di orishi rishi eroja afaralokun ti o wulo. Owo ti o joju ni awon ile ishe yi n san,won si n toro imontoto lori wara ti a fee ta fun won,toripe ogidi wara ti o man nikan ni won fee ra.
Current language
Yoruba
Produced by
Agro-Insight