<<90000000>> viewers
<<240>> entrepreneurs in 17 countries
<<4135>> agroecology videos
<<105>> languages available

Ki ko wara lo si aaye akojo

Uploaded 7 years ago | Loading

Awon Kokoro aifojuri kan ni o maa n ba wara je,kia ni won o dagba ti won o si bi omon lati ba wara je,eyi maa n shele ninun wara gbigbonan ju tutu lo. Ki a tete gbé wara de aaye akojo laarin ogbon isheju ti won ba fun  un bibeekoo yoo tete baje. Ni aaye akojo ni won o ti soo di tutu ni kia ki o le ku ni daada.

Current language
Yoruba
Produced by
Agro-Insight
Share this video:

With thanks to our sponsors