<<90000000>> viewers
<<266>> entrepreneurs in 18 countries
<<4647>> agroecology videos
<<107>> languages available

Bawo ni a o ti so ilè di olora fun ogbin alubosa

Uploaded 7 years ago | Loading

Gégé bi awon ohun ogbin ti o ku alubosa a maa gbadun ora inun ilè ni igba ti o ba n fa omi ilè mun,ora inun ilè  yi ni onje fun awon ohun ogbin,sugbon ekan alubosa kopo bee won ko si wo ilè pupo won ko lee ri onje inun ilè je ayaafi eyi ti o ba wa ni itosi okè erupe ni ibi ti ekàn won wa.

Current language
Yoruba
Categories
Produced by
Agro-Insight
Share this video:

With thanks to our sponsors