Shishe amojuto arun alubosa
Uploaded 7 years ago | Loading
10:00
Alubosa a maa hu ni orishi rishi onan ni otooto,shugbon ni akoko ojo opoloo onan ni o shi ka’lè ti alubosa fi le ko arun ti o le baajé. Alubosa yin yoo tete ko orishi rishi arun ni apa ibi ti omi n gunro si ju ninun oko yin. Orishi rishi ami ni orishi rishi arun alubosa maa n mun wa,sugbon opolopo arun yi naa onan kan naa ni a fi le she amojuto won.
Current language
Yoruba
Produced by
Agro-Insight