<<90000000>> viewers
<<240>> entrepreneurs in 17 countries
<<4135>> agroecology videos
<<105>> languages available

Ebè alubosa

Uploaded 7 years ago | Loading

Ogbin alubosa ni’lo erupe ti o félé ti o si ni alaafia. E she afikun igbonse awon eran abi ilèdu. Ni akoko ojo dandan ni ki a je ki ebe alubosa wa o ga ki ekàn re o le wa ni alaafia ki o ma jerà. Ti e ba n gbin koro alubosa ti o dara gbogbo eyi ti e bag bin ni yoo hu eyi ko ni je ki e gbin pupo. Alubosa ni’lo alafo daada lati le hu daada,torinaa e ma gbin won sun mon araawon.Ori ilà bii cèntimita marunsi mewa ni ki e gbin won si ki o si wo’lè to bii cèntiita kan, ki e pada fi erupe ni iwonba boo.

Current language
Yoruba
Categories
Produced by
Agro-Insight
Share this video:

With thanks to our sponsors