Sishe elo obe kpelu soja
Uploaded 4 years ago | Loading
9:57
Jakejado agbaye, awon eyan ma fi elo obe sinu oun’je won ko le fi ni adun to dara. Ni iwo-oorun Africa okpo obe ni won n’se kpelu elo obe ti won she kpelu irugbin igi soja. Ni orile ede mali, soumbala ni won n’kpe elo obe yin. Gige awon igi lokpolokpo ni awon agbegbe ooru sahel je ki soumbala showan ko situn gbowosi. Bi otile jekpe won ma saba lo cube, awon obirin orile ede mali tun wa ona mirin, ni won fi n’gbin soumbala ti won n’she nikpase soja.
Current language
Yoruba
Produced by
AMEDD